Link to home pageLanguagesLink to all Bible versions on this site
Saamu 117
1 Ro 15.11.Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;
ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
2 Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa,
àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé.
 
Ẹ yin Olúwa!

<- Saamu 116Saamu 118 ->